Get the lyrics of “Igbowo Eda” by Tope Alabi. You can also download the PDF file below for offline use.
LYRICS
Alagbawi mi onigb?w? to y? mi loko iya o
Alagbawi mi onigb?w? to y? mi l’okun
Modupe, ose, to san igbese mi
Modupe, ose, to san gbese mi
Iwo lo yo mi loko iya ti mo ko ori mi bo
Àní iwo lo yomi ninu oko oshi ti mo kese mi bo
Ose, modupe, to san igbese mi
Ose oo, modupe, to san gbese mi
Alagba wi mi (alagba wi mi)
Onigbowo eda (onigb?w? mi)
Oseun, to san gbese mi (ose oo)
?p? ni mo wa du nitemi (alagbawi mi, onigb?w? mi o ?eun to san igbese mi)
Orun yo tori mi
Mo d’ominira a tu mi sil?
Emi aji gbese ojosi
Agbelebu tu mi sile oo
Eleso ajeku, oti ko gba wole
Eleso ajeku, oti ko igba wole (kogaba wole ko)
Alagbawi mi, onigb?w? mi
Oseun to san gbese mi
Alagbawi mi, onigb?w? mi
Oseun to san gbese mi
Iyan ki s’?gb? isu laye
Ma fo tolori we panduku
Ibi isubu yato si ibi idide
Ogba edeni lakoba ti wa
A tun ipin ?da yan lati ibi agbari
A tori aye se ni calvary
Agbelebu ibi ifese jin
A ká iboju kuro aso ip?nju faya
Alapa pe oniya ji oju re mo
Ko je ni fi ni korogodo
Alapa pe ti kogba wole
Alagbawi mi (ose Olodumare)
Onigb?w? mi (alagbawi onigb?w? mi)
Ose, to san igbese mi (ose ooooo)
Alagbawi wi mi (alagbawi mi)
Onigb?w? mi (onigb?w? eda)
Ose, to san igbese mi
Ak?sil? gbese ti par?
Kosi wulo afi jo ko mo
Ajigbese bo logun a sin gba
?j? ra jí gbese ateni dogo
Eniti a d?ni tin fonka
Eku ibanuje wa di erin
Ajigbese ati adogo a ti bo
Igi ti da okun ti ja
Awa ti y?
Eni to wo igi ohun lo ri iye
Ominira ti de
Alagbawi mi (ata dogo)
Onigb?w? mi (atoni gbese)
Ose, to san gbese mi (ata ji gbese awa m?t?ta)
Alagbawi mi (la ba bo loko iya o)
Onigb?w? mi (laba bo loko eru)
Ose, to san gbese mi (opelope onigb?w? alagbawi eda oo)
?p? onife alail?gb?
F’ogo folugbala t’ojoko nite anu
?p? alagbawi igb?w? eda oo
Owaye wa fi iku agbekorun mi t?l? jona
O ko mi ni la iya to ni K?la aye o le ko o
Emi mimo wa di ogun ibi si iye fún emi
Mo d’ominira ah ah mo do mo
Mo d’ominira eh eh moyege
Baba mi lo laye at’?run, mo d’ominira
Mo d’ominira eh eh, moyege
Mo d’ominira ah ah, mo d’omo (mo di ?m? lat’oni l?)
Mo d’ominira eh eh, mo yege (sha r?ni to s?b? p?lu emi)
Mo d’ominira ah ah, mo d’omo (b??ni ?m? ni mi)
Mo d’ominira eh eh, mo yege (kò sí gbese l?rùn mi ?j? lo san gbogbo r?)
Jesu san gbese mi tan, mo b? l?w? aninilara
Alagbawi san tan mo d?ni aponle mo d’omo, mo d’omo mo d’ominira oooo
Mo yege mo jo’gun aye raye (mo jo’gun aye raye iye ni temi)
Mo d’omo, mo d’omo, mo d’ominira oooo
Mo yege, mo jo’gun aye raye
Mo d’ominira ah ah, mo d’omo
Mo d’ominira eh eh, moyege (alagbawi lo sa sepe Ise Aye mi)
Mo d’ominira ah ah, mo d’omo (onigb?w? ohun lo sa sepe Ise mi o)
Mo d’ominira eh eh, mo yege (ko sí wulo afi jogo mo o)
Listen to the song below and download PDF file.