Get the lyrics of “Omo’ba” by Pelumi Deborah. You can also download the PDF file below for offline learning purpose.
LYRICS
Omo’ba – Pelumi Deborah
Şeb’ emi na re o, omo Oba
alemi na re o, omo Oba
Şeb’ emi na re o, omo Oba
alemi na re o, omo Oba
(why look any further)
şeb’ emi na re o, omo Oba
eni Oba nke
eni Oba nge
eni Oba n wo
eni Oba ntoju
Oba lo to mi dagba
Oba lo womi dagba
Oba lo ran mi ni şe
Oba lo f’ ami simi Lara
Oba lo da ororo lemi lori
O f’ade iyin de mi lori
O f’ ade ogo demi lori
O f’ ade ewa demi lori
Ohun lo ni ki n duro deeded
Olohun wa lehin mi bi akoni eleru
O ni awon omo kiniun
won a ma şe alaini
ebi a si maa pawo
Şugbon awon to duro de Oluwa
won ko ni ş’ alaini ohun to dara
emi ti gbe Oluwa ka iwaju mi nigbagbogbo
nitori O wa lehin mi eh..
aki yio şi mi nipo
won o le şi mi nipo eh…
mo ni won o le şi mi nipo
emi o şee şi nipo
tori Oba lo ran mi nişę
Oba lo ran mi nişę
baa ranni nişę Oba aa fi toba je (2x
Oba lo ran mi nişę
Ohun lo ni ki n ma bęru
Ohun loni ki n ma foya
Ohun lo ni ki n te siwaju
Şeb’ emi naa re oo, omo Oba
a lemi naa re o om’ Oba
(I can’t help it)
şeb’ emi naa re oo eeehhhh
şeb’ emi naa re o om’ Oba o eh..
şeb’ emi naa re omo…
şeb’ emi naa re oo
Ajikę
Ajigę
Apekę
Asakę
Ayanfę
Ololufe mi lo pemi
O ni kin duro deede
O ni kin maşe bęru
O ni kin maşe foya
şeb’ emi na re
res: Omo’ ba
şeb’ emi na re
res: Omo’ ba
all: Oba nkę mi
Oba n wo mi
Oba lo n dari ęsę mi
emi naa re omo’ ba
Listen to the song below.